Beast and Peace lyrics by Mohbad

Beast and Peace lyrics

Beast and Peace lyrics by Mohbad
Beast and Peace lyrics

Beast and Peace lyrics by Mohbad portray him as a calculated individual who finds it amusing when others perceive themselves as smarter. The song delves into how Mohbad organizes his life to avoid unnecessary complications.

Beast and Peace suggests the importance of viewing people from one’s perspective and not assuming superiority. Mohbad uses the lyrics to highlight his intelligence and strategic approach to life, emphasizing that he knows what he’s doing. The song also touches on his ability to handle personal matters and his career through careful planning.

Mohbad – beast and peace lyrics 

(The winds will come)
(To steal the words I say) Imole
Ahn

Like Audio

Ahn, mó silent mood, but beast ní mí
Mo lé cause violence but still, peace ní mí
You don’t have to hurt me, before you win
You don’t have to kill somebody before you sin
Óṣá lé browse, láì dè ló sub oh
Òde lé go far without God oh
So, mó dúró t’Olùwà
So, kò kín ṣe irú wá
Even tọbà fún yín làbọ pẹ’lú spoon,
ẹ lè j’ojú wá

Èmi má dẹ tí bad, láti àyé la’dì-la’dì
Láti àyé 1990 tó ńlù beat pati-pati
Èmi tímo feel bad,
mó dẹ tí feel good
Now, mó feel better,

Surulere bí Ojuelegba
Torípé mó wọ ńkán, wọn sọ pé mowà on drug
Now, mowà on top, life mí òdẹ ní contour
Mó pàwọn ni Naija, ó tún báwọn ní London
Fún wọn ní KPK, Ponmo, Light boy wo, mo ńta’na
(Light-boy mo ńta’na)

Uh, mummy mí àti daddy mí, wọn kàn ló ń question mí
Wọn ní, “Ìbò l’otí rí vibe yi, ṣé ọwọ demon?”
Àwọn tọ senior mí, wọn bèrè,
“Where you see money?”
Àwọn tí mó jùlọ, wọn photocopy mí

READ MORE  Chike – Music No Need Permission to Enter Your Spirit ft. Mohbad

First cashout mí, ọmọ ìyá,
mó dè fí rá bazooka
Mo kó fún àwọn sharp shooter
Ẹ má bínú tọbá dá sí’ta
Tra-ta-ta-ta-ta-ta fún àwọn fake nigga

Àwọn t’ofẹ shame mí
Wo, èmi wá shameless
Wọn fẹ stain white mí,
but mo wá stainless
Àwọn nigga tọ leave mí,
wọn lé rí realness

Torí pé silence mí,
no mean say na weakness
Shoutout sí Iba J, Diarra, pẹ’lú Hayan
CY, Darosha, Prime Boy
Spending with my daddy, life mí wá splendid
Ológo, Zomo, TIA, Bella

(Chukwuchilly)
Soul
Mí ṣámọ
Wọn ní irú ẹ
Irú ẹ tóní, kò kíń ṣe original
(Boombah)
O fẹ, o fẹ sùn mó mí
But, kò kíń ṣe òun gan-gan

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*